Ẹranko elégungun /ˈvɜːrtəˌbrəts/ ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí (subphylum) ẹranko elégungun ma ń sábà ní /ʔə/ chordates (egungun ẹ̀yìn). Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumChordata, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje (69,963) níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn.[2] Lála àwọn àkójọpọ̀ àwọn ẹranko elégungun ni:
Ẹranko elégungun /ˈvɜːrtəˌbrəts/ ni ó kó gbogbo ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ lára ẹbí (subphylum) ẹranko elégungun ma ń sábà ní /ʔə/ chordates (egungun ẹ̀yìn). Ẹranko elégungun ni wọ́n jẹ́ púpọ̀ níní ẹbí phylumChordata, tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lé láàdọ́rin àti ọgórùn ún ó dín méje (69,963) níye ẹ̀yà tí a gbọ́ nípa wọn. Lála àwọn àkójọpọ̀ àwọn ẹranko elégungun ni:
ẹja aláìnírùngbọ̀n Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun onírùngbọ̀, ni a ti lè rí àwọn ẹranko bíi ẹjà cartilaginous (ẹja ṣáàkì, rays, àti ratfish) Ní abẹ́ ẹ̀yà ẹranko elégungun tetrapods,ni a ti lè rí amphibians, afàyàfà, ẹyẹ àti àwọn ẹranko afọ́mọlọ́mú gbogbo. ẹja eléegun púpọ̀