Efinrin (Látìnì: Ocimum gratissimum) ni wọ́n tún ń pè ní "clove basil", tàbí "African basil",[1] tí àwọn Hawaii mọ̀ sí "wild basil",[2] jẹ́ ẹ̀yà ewé kan tí ó wá tí ó sì wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, Madagascar, apá Gúsù ilẹ̀ Asia, ilẹ̀ Bismarck Archipelago, wọ́n ń gbìín ní Polynesia, Hawaii, Mexico, Panama, West Indies, Brazil, àti orílẹ̀-èdè Bolivia.[3]
Efinrin ni wọ́n ewébẹ̀ tàbí egbògi tí ó wọ́pọ̀ jùlọ ní ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀, tí wọ́n sì ń pèé ní àwọn orúkọ wọ̀nyí nínú èdè wọn.
Efinrin (Látìnì: Ocimum gratissimum) ni wọ́n tún ń pè ní "clove basil", tàbí "African basil", tí àwọn Hawaii mọ̀ sí "wild basil", jẹ́ ẹ̀yà ewé kan tí ó wá tí ó sì wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, Madagascar, apá Gúsù ilẹ̀ Asia, ilẹ̀ Bismarck Archipelago, wọ́n ń gbìín ní Polynesia, Hawaii, Mexico, Panama, West Indies, Brazil, àti orílẹ̀-èdè Bolivia.