Àdàkọ:Infobox medical condition (new)
Hantavirus tàbí orthohantavirus jẹ́ kòkòrò ẹ̀ràn àìfojúrí tí ó máa ń jẹyọ lára eku.[3] Ó jẹ́ ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí tí ó máa ṣẹ̀yọ lára eku, ṣùgbọ́n kìí ṣe wọ́n ní ìjàmbá kankan.[3] Ènìyàn lè kó ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí, Hantavirus láti ara ìtọ̀, irọ́ tàbí imìgbẹ́ eku. Èyí lè fà àìsàn ìbà tí wọ́n ń pè ní hantavirus hemorrhagic fever with renal syndrome (HFRS), tàbí èyí tí wọ́n ń pè ní hantavirus pulmonary syndrome (HPS), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí hantavirus cardiopulmonary syndrome (HCPS),[4] àwọn àìsàn mìíràn tí ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí yìí máa ń fà, kò ì tí ì ṣẹ̀yọ lára ènìyàn. [5] HPS (HCPS) yìí jẹ́ àrùn tí ó máa ń jẹ mọ́ èémí nípa fífa òórùn ìgbẹ́ tàbí ìtọ̀ eku tí ó ti ní ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí Hantavirus símú."[4]
Ènìyàn lè ko àgbákò àrùn tí ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí Hantavirus máa ń fà bí ènìyàn bá fara kan ìgbẹ́ eku, ṣùgbọ́n lọ́dún 2005, ìròyìn gbé e pé ẹni kan kó àrùn náà lára ẹlòmíràn ní Gúúsù Amẹ́ríkà (South America).[5]
Wọ́n ṣẹ̀dá orúkọ yìí, Hantavirus láti ara odò kan tí wọ́n ń pè ní Hanta lórílẹ̀-èdè South Korea, níbi tí àrùn náà ti kọ́kọ́ ṣẹ́yọ ,[6]
Àdàkọ:Infobox medical condition (new)
Hantavirus tàbí orthohantavirus jẹ́ kòkòrò ẹ̀ràn àìfojúrí tí ó máa ń jẹyọ lára eku. Ó jẹ́ ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí tí ó máa ṣẹ̀yọ lára eku, ṣùgbọ́n kìí ṣe wọ́n ní ìjàmbá kankan. Ènìyàn lè kó ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí, Hantavirus láti ara ìtọ̀, irọ́ tàbí imìgbẹ́ eku. Èyí lè fà àìsàn ìbà tí wọ́n ń pè ní hantavirus hemorrhagic fever with renal syndrome (HFRS), tàbí èyí tí wọ́n ń pè ní hantavirus pulmonary syndrome (HPS), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí hantavirus cardiopulmonary syndrome (HCPS), àwọn àìsàn mìíràn tí ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí yìí máa ń fà, kò ì tí ì ṣẹ̀yọ lára ènìyàn. HPS (HCPS) yìí jẹ́ àrùn tí ó máa ń jẹ mọ́ èémí nípa fífa òórùn ìgbẹ́ tàbí ìtọ̀ eku tí ó ti ní ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí Hantavirus símú."
Ènìyàn lè ko àgbákò àrùn tí ẹ̀ràn kòkòrò àìfojúrí Hantavirus máa ń fà bí ènìyàn bá fara kan ìgbẹ́ eku, ṣùgbọ́n lọ́dún 2005, ìròyìn gbé e pé ẹni kan kó àrùn náà lára ẹlòmíràn ní Gúúsù Amẹ́ríkà (South America).
Wọ́n ṣẹ̀dá orúkọ yìí, Hantavirus láti ara odò kan tí wọ́n ń pè ní Hanta lórílẹ̀-èdè South Korea, níbi tí àrùn náà ti kọ́kọ́ ṣẹ́yọ ,