dcsimg

Proturan ( Yoruba )

provided by wikipedia emerging_languages

Protura, tàbí àwọn proturan, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ conehead,[1][2] jẹ́ àwọ́n ẹrankó kékèké (<2 mm ní gígún), tí wọ́n ń gbé inú iyẹ̀pẹ̀, wọ́n kéré tó bẹ́ẹ̀ tí a kò ṣàkíyèsí títí di ogún ọ̀rundún sẹ́yìn. Protura jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn hexapod tí a kà sí àwon kòkòrò insects, ti a má ań kó wọn sí àyè wọn lọ́tọ̀.[3].

Àwọn ìtọ̣́kasí

  1. "Proturans / Coneheads".
  2. "Order Protura - Coneheads". http://bugguide.net bugguide.net, hosted by Iowa State University Department of Entomology.
  3. Charles S. Henry (2005)
license
cc-by-sa-3.0
copyright
Awọn onkọwe Wikipedia ati awọn olootu

Proturan: Brief Summary ( Yoruba )

provided by wikipedia emerging_languages

Protura, tàbí àwọn proturan, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ conehead, jẹ́ àwọ́n ẹrankó kékèké (

license
cc-by-sa-3.0
copyright
Awọn onkọwe Wikipedia ati awọn olootu