Microlophus habelii, tí wọ́n sábà mọ̀ sí alángbá àpáta Marchena jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Marchena.[2]
Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, habelii, dá Simeon Habel, onímọ̀ àdáyébá ọmọ jamaní-Amẹ́ríkà lọ́lá.[3]
Wọ́n fí M. habelii sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà Tropidurus, tí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ tẹ́lẹ̀.[1]
Microlophus habelii, tí wọ́n sábà mọ̀ sí alángbá àpáta Marchena jẹ́ ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Marchena.