Microlophus koepckeorum, tí wọ́n mọ̀ sí Frost's iguana, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní Chile àti Peru.[1]
Wọ́n fi orúkọ tí wọ́n ń pèé gangan, koepckeorum, dá Hans-Wilhelm Koepcke àtí Maria Koepcke, tí wọ́n jẹ́ ọkọ àti ìyàwó, onímọ̀ ẹyẹ ọmọ orílẹ̀ èdè jamaní tí wọ́n bí sị́ Peru.
Microlophus koepckeorum, tí wọ́n mọ̀ sí Frost's iguana, jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní Chile àti Peru.